Eranko ile, eranko igbo Won yin baba l'oke
Awon alaini, awon tan ti ni
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe baba be l'oke
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe looto o be l'oke
You don't have to wait till you feel the pain
It's not too late, to be grateful
Pe mo wa laye, mo wa laye
Gbogbo ti mo ni, ma fin yi o l'ogo
Believe this world a better place
Wo mi, bi mo se f'ope ye baba